Home ÀRÒJINLẸ̀ Ọmọbìnrin ọdún méjìdínlógún ti s’aláìsí lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ mẹ́ta tí ó ṣe ìgbéyàwó.
ÀRÒJINLẸ̀ - orisiirisii - Orisirisi - June 26, 2019

Ọmọbìnrin ọdún méjìdínlógún ti s’aláìsí lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ mẹ́ta tí ó ṣe ìgbéyàwó.

Chinwendu Promise Ifeabunandu omo odun mejilelogun ti s’alaisi leyin ose meta ti o se igbeyawo.

Oloogbe Chinwendu se igbeyawo pelu Chukwuebuka Ifeabunandu ni April 28 o si s’alaisi ni May 19, leyin aisan ranpe.

Nigba ti won bere nnkan to sele si aburo re lowo egbon re okunrin, Nwakanwa Okafor, o ni “iku ojiji” ni.

Won ma sin Chinwendu si ilu oko, Nnulukwu village ni Ichida ni Aniocha local government area ni ipinle Anamnba lojo Saturday, June 29.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…