Ọlọ́pàá ti gbé bàbá àádọ́rin ọdún fún ẹ̀sùn pé ó fi ipá bá ọmọ ọdún márùn-ún lòpọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Imo.
Olopaa ipinle Imo ti gbe baba aadorin odun, Pa John fun esun pe o fi ipa pa omo odun marun-un lopo ni June 14.
Ajafetoo ati olori ero Behind Bars, Prince Emefiana Gwamnishu, ti o gbe isele naa si ori afefe ni, won ka baba naa ninu igbo nibi ti o ti n ba omo naa ni asepo.
O ni akope kan lo ka ninu igbo nibi ti o ti n se ise ibi naa. O be akope naa ki o ma sofun enikekeni, o wa lo sapomo si Abia. Nigba ti mo gbo isele naa, emi ati awon egbe mi lo si Mbaise lati ri awon oloye ki a si da ogbon ati mu. Won so fun pe emi ati egbe mi n ro bi a se ma yanju oro lai sofun olopaa. O si wa, bi a se mu ni ana June 25, won ma gbe lo si ile ejo ni ola, June 27.
Harrison ni baba naa wa ni ago olopaa ni Mbaise, ipinle Imo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…