Home orisiirisii Ọkùnrin awakọ̀ tírọ̀kì ti pa ara rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa.
orisiirisii - Orisirisi - June 26, 2019

Ọkùnrin awakọ̀ tírọ̀kì ti pa ara rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa.

Arakunrin omo odun marunlelogiji ti n wa oko tiroki, Oliver Osieme, ti pa ara re sinu yara re ni agbegbe Etegwe ni Yenogoa local government ni Bayelsa ni ana June 25.

Oliver subu sinu ironunati ibanuje leyin ti o padanu ise re. Oko re ni isoro ti o si nilo owo pupo lati tunse.

Ni ana, leyin ti iyawo ati gbogbo molebi ti ba oro aje jade, Oliver so okun mo faanu, o si pa ara re.

Aburo iyawo re lo ri oku re leyin ti o ti ile iwe de.

Agbenuso olopaa ipinle, SP. Asinim Butswat, lo fi idi ere isele naa mule, o si ni iwadii si n lo lori re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…