Home ÀRÒJINLẸ̀ Kàyéfì : Wọ́n ti rí òkú ọkùnrin tí wón ń wá ní ìpínlè Rivers.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 26, 2019

Kàyéfì : Wọ́n ti rí òkú ọkùnrin tí wón ń wá ní ìpínlè Rivers.

Won wu oku arakinrin omo ipinle Rivers, Inedukoba Charles Tyger, jade ni ojo Tuesday, June 25 lati inu saree kan ni Abalama Sandfield Asari-Toru local government ni ipinle Rivers, leyin opolopo osu ti awon molebi ati ore ti n wa.

Ore oloogbe na, Ibiye Dokubo, ti so lori Facebook ni February 26, pe awon n wa Tyger. O ni Tyger ati iyawo re jo ni oro aawo nitori Tyger fun obinrin imii loyun.

Leyin opolopo iwafii fun opolopo osu, won wu oku Ogbeni Tyger ni ana, June 25 ni agbegbe Asari-Toru local government.

Iyawo re, Ajemina Douglas, ni won so pe o pa oko ti o si sin oku re si abe afara. Awon olopaa gbe, o si mu won lo si saree ti o sin oko re si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…