Home iroyin Jíjá ìwé láti gbé mi jẹ́ ìlànà ẹ̀gbin tí ó lọ jìnnà jù – Alaga Innoson Motors, Innocent Chukwuma.

Jíjá ìwé láti gbé mi jẹ́ ìlànà ẹ̀gbin tí ó lọ jìnnà jù – Alaga Innoson Motors, Innocent Chukwuma.

Innocent Chukwuma, alaga Innoson Motors ti ni jija iwe lati gbe oun ti ile ejo Èkó ja, je egbin ilana ile ejo.

Gege bi gbolohun ti oga Innoson naa towo bo, ni ase na je asan, ki si ni ese ninu ofin, oni ile ejo naa o ni ijoba to tọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…