Home Entertainment “Ẹ̀yin Òǹṣèré, ìgbà tí yàtọ̀, ẹ ní láti ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn fáànù yín” – Don Jazzy.

“Ẹ̀yin Òǹṣèré, ìgbà tí yàtọ̀, ẹ ní láti ní ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn fáànù yín” – Don Jazzy.

Ni aaro yi, Don Jazzy n salaye bi ibasepo pelu awon faanu awon akorin se pataki si won.

O ni “Eyin akorin, igba ti yato o. Oro Chris brown yii to lati he ki e mo pe omi ti po ju garri lo. E ma ba awon faanu yin se. Eyi kii se akoko lati ma a ruga. Ako Twitter ati Instagram ko ran yin.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…