Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Àwọn Super Eagles ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ padà.

Àwọn Super Eagles ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ padà.

Awon Super Eagles Naijiria ti bere ise pada, leyin ti won da ise sile nitori won o fun won ni bonosi to ye ni Africa Cup of Nations ni Egypt nitori awon agbagba ninu ere boolu ti won da si.

Won gbe lati tirani ni Alexandria, leyin ogbon iseju si akoko, leyin ti Nigerian Football Federation (NFF) ti ni won ma fun won ni bonosi ere 1-0 ti won gba pelu Burundi ni ojo Satide, ni opin ose.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…