Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn ajínigbé tí pa arákùnrin ọmọ Nàìjíríà kan, lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí ó dé sí Nàìjíríà láti Istanbul, Turkey.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 26, 2019

Àwọn ajínigbé tí pa arákùnrin ọmọ Nàìjíríà kan, lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí ó dé sí Nàìjíríà láti Istanbul, Turkey.

Awon ore ati molebi ti n s’ofo iku arakunrin kan, Uwaoma Ifeanyi lati Orlu, ipinle Imo lori Facebook.

Won ni won ji okunrin ti o ni omo meji naa gbe,won si pa a ni ojo Sunday June 23. Apa ota ibon po gan ni ara re.

Gege bi ore, Chris Barry se so, oloogbe Ifeanyi kuro ni ile re ni Istanbul ni ago meji koja ogbon iseju aaro ni June 22, lati lo wo oko baalu wa si Naijiria nibi ti won ti paa leyin wakati die.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…