Home orisiirisii Arákùnrin fún ẹni tí ń kiri ọjà ní ẹ̀bùn ìdá ọgọ́rùn-ún nnkan tí ó rà nitori ó fi ọkàn tọ.
Arákùnrin fún ẹni tí ń kiri ọjà ní ẹ̀bùn ìdá ọgọ́rùn-ún nnkan tí ó rà nitori ó fi ọkàn tọ.
Arakunrin ti salaye bi oun se ra oja ninu goslow ti oun o si ri owo naa san lesekese awon eni ti n ta oja naa si ni ki o fun oun ni owo naa nigbamii.
O ni oun ra waya 2500naira lowo ontaja ninu goslow. Amo ki oun to yo owo sita, awon oko ti n rin lo, oun o si ri owo fun pe oun si fe da waya naa pada, amo nitori okunrin naa fe ta oja.
Arakuntin ti n ta oja naa si ni ki oun ma mu lo ki oun si san owo nigbamii. O ni o gba kaadi oun, o si sendi nomba ile ifowopamo re si oun.
Nigba ti oun ma fun ni owo naa, oun fun ni 5,000 naira yala 2500 naira, gege bi ebun nitori o gba oun gbo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…