Home iroyin Wọ́n ti gbé arábìnrin kan tí ó p’arọ́ pé òṣìṣẹ́ Sawo-Olu ní òun ní Embassy Italy láti gba físà.

Wọ́n ti gbé arábìnrin kan tí ó p’arọ́ pé òṣìṣẹ́ Sawo-Olu ní òun ní Embassy Italy láti gba físà.

Won ti gbe arabinrin kan ti o paro pe osise lati ofisi gomina ipinle eko ni oun lsti le gba fisa fun awon eeyan kan.

Ninu gbolohun ti oloye akowe si Gomina Babatunde Sanwo-Olu, Gboyega Akosile so, o ni, obinrin naa, ran email si Embassy Italy in eko, o si dibo bi osise ijoba ipinle eko lati bere fun fisa fun awon omo Naijiria kan,ti awon gan o mo.

Akosile ni embassy naa ko leta si ofisi gomina lati mo boya ooto ni arabinrin naa n so, nigbs ti won ri pe iro ni, won ba lo fi olopaa gbe obinrin naa ti won si bere oro lowo re.

Akosile ni arabirin naa ni oun o mo nnkankan nipa re pe won towo bo email oun ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…