Sójà na arákùnrin ọlọ́kadà kan, lẹ́yìn tí kò san owó iṣẹ́ rẹ̀ fun.
Olokada kan n je irora lowo lowo bayii ni ipinle Bayelsa, leyin ti soja kan naa gidi gan, ti ko si san owo ise re fun.
Enikan ti n je Uncle Whisper lo so lori Facebook pe,
“se ofin kankan wa pe ki awon soja ye ma san owo fun oko? O ni oun gbo pe arakunrin naa je omo Bayelsa kati Ogbia, o ni o gbe soja kan rin irin ajo lo si ibi orisirisi ti o jinna pe nigba ti pada de beesi soja naa, ko fe san owo fun okunrin naa yala o luu bi i bara ni. Amo oun gbo pe wonbti gbe okunrin lo si ile iwosan. Oun si fe ki awon ti isele bayii kan wa nnkan se si oro naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…