Home iroyin Reno Omokri gbé fídíò sójà tí ó pàdánù ẹsẹ̀ rẹ̀ lójú ogun pẹ̀lú boko haram s’órí afẹ́fẹ́.

Reno Omokri gbé fídíò sójà tí ó pàdánù ẹsẹ̀ rẹ̀ lójú ogun pẹ̀lú boko haram s’órí afẹ́fẹ́.

Reno Omokri n fi atileyin han fun awon soja ti n ja fun Naijiria, o fi fidio naa han pe won ki n se ojo.

Aworan naa n fi soja kan ti n japoro lowo han latari ogun ti o lo dajuko pelu awon boko haram.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…