Home iroyin Ọlọ́pàá ti kó àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n fi ipá ba obìnrin ọmọ ọdún mẹ́tàlélógún tí ó ní àrùn ọpọlọ lòpọ̀ ní Anambra.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 25, 2019

Ọlọ́pàá ti kó àwọn ọkùnrin méjì tí wọ́n fi ipá ba obìnrin ọmọ ọdún mẹ́tàlélógún tí ó ní àrùn ọpọlọ lòpọ̀ ní Anambra.

Olopaa ipinle Anambra ti ko awon okunrin meji ti won fi ipa ba obinrin to ni arun opolo lòpọ̀.

Agbenuso, SP Haruna Mohammed ni ojo Monday, June 24 ni nnkan bi ago meta osan, awon olopaa agbegbe Oyi mu awon okunrin meji naa Okwuchukwu Anyanwu omo odun merindinlogoji ati Emeka Odoh omo odun marundinlogbon, ti won je omo Ezi Umunya ni Oyi LGA ni ipinle Anambra.

Awon okunrin na ni ojo Sunday, June 23 ni ago mokanla aaro fi ipa ba Nwanneka Nwaizu, omk odun metalelogun lopo, o je eni to ni arun opolo ko si mo nnkan ti won se fun.

Iwadii si n lo lori isele naa, won si ma to gbe won lo si ile-ejo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…