Home iroyin Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Rivers tí gba ọmọ ọdún mẹ́jọ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ajínigbé.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - Social Good - June 25, 2019

Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Rivers tí gba ọmọ ọdún mẹ́jọ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ajínigbé.

Awon olopaa ipinle Rivers ti gba omobinrin odun mejo ti won jigbe sile.

Won ji Sophia Ehis gbe ni ile awon obi re ni Nkpor village Rumuolumeni Port Harcourt ni May 11, 2019.

Awon olopaa ago olopaa Rumuolumeni ti gbe awon obinrin meji ti won fura si pe won lowo si bi won se ji Ehis gbe. Awon naa ni:

1. Patience Madukwe omo aadota odun lati Osidioma Ngwa Aba, ipinle Abia.
2. FannobUkoaha omo merinlelaadota odun lati Umuakoma Alaoji Aba, ipinle Abia.

Omo naa wa ni alaafia won si ma fa ale awon obi re lowo leyin ti won ba se iwadii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…