Home ÀRÒJINLẸ̀ Ọkùnrin kan ti fò afárá sínú omi láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ ni Eko.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 25, 2019

Ọkùnrin kan ti fò afárá sínú omi láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ ni Eko.

Okunrin kan ti gbiyanju lati gba emi ara re, o fo afara sinu omi.

Adupe pe awon apẹja wa ni itosi ti won si sare gbe okunrin naa sinu oko oju omi won.

Ko pe ti oko oju omi ti won fi n gba awon eeyan sile de, ti won si gbe okunrin naa sinu e.

A ko mo ipo ti alaafia okunrin naa wa bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…