Home iroyin Àwọn tí wón ń yọ́ ọjà gbé w’ọ̀lú ti yín ìbọn pá òṣìṣẹ́ custom, Yakubu Shuaibu sínú igbó.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - ỌRỌ̀-AJÉ - June 25, 2019

Àwọn tí wón ń yọ́ ọjà gbé w’ọ̀lú ti yín ìbọn pá òṣìṣẹ́ custom, Yakubu Shuaibu sínú igbó.

Awon ti n yo oja gbe wolu (smugglers) ti yin ibon pa osise custom, Yakubu Shuaibu sinu igbo ni ipinle Ogun.

Gege bi agbenuso Nigeria Customs Service (NCS), Federation Operations Unit (FOU), Zone A, Jerry Attah se so, ofisa miiran farapa leyin ti awon eni yii duro de won lona nigba ti won n pada si aye won, l ẹ yin ti won gba iresi ti won fe yo gbd wole.

O ni : “ won n se patiro lowo, won ti gba iresi lowo awon eeyan, nigba ti won n gbe iresi naa lo si aye wo, ni won da won lona.”

Won yin ibon fun oloogbe Shuaibu ni ilu Akinrun, Oja Odan ni Yewa North LGA o si ku leyin ti o farapa.

Agbenuso naa ni won ti sinku ofisa naa gege bi asa musulumi, won o si ti ri enikeni mu, amo iwadii si n lo lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…