Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn Super Eagles ti da iṣẹ́ sílẹ̀ ní Egypt nítorí wọ́n ò san àláwásìn wọn.

Àwọn Super Eagles ti da iṣẹ́ sílẹ̀ ní Egypt nítorí wọ́n ò san àláwásìn wọn.

Awon Super Eagles ti da ise sile ni Egypt nitori won o san alawansi won. Gege bi osise BBC nipa oro ere idaraya, Sulaimon Folarin se so, awon agbaboolu naa ti won wa ni Egypt fun AFCON2018 ti ko lati lo tireni lonii June 25 nitori won o san alawansi won.

Awon agbaboolu naa ni won o ti san $10,000 bonosi 1-0 ti won gba pelu Burundi.

Aare NFF, Amju Pinnick so fun awon oniroyin ni Egypt pe won ni owo naa lati fun awon agbaboolu naa ni naira, amo eon ko fe gba a, nitori ti won ba se owo naa, awon agbaboolu naa ma fi ara gba ofo ti ba wa nibe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…