Home iroyin Arákùnrin tó ṣèṣe padà sí ilé lẹ́yìn agunbaniro rè tí gùn àbúrò rẹ̀ pa.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 25, 2019

Arákùnrin tó ṣèṣe padà sí ilé lẹ́yìn agunbaniro rè tí gùn àbúrò rẹ̀ pa.

Àwọn olopaa ipinle anambra ti gbe arakunrin omo odun mejidinlogbon, Victor Ohale, fun esun pe o gun aburo re, Kelechi Ohale, pa ni ile won ni Awka lonii J un ne 25.

Ninu gbolohun ti awon olopaa fi kale, won ni Victor ti o je giraduati eka ofin lati ile iwe giga Nnamdi Azikiwe, to sese pada sile leyin odun kan to lo fun agunbaniro ni ipinle Zimo. Oun ati aburo re jo ni oro awo t i o si di ija ni aaro yii. Victor si ko oríṣi obe marun sita, ti o se fi gun aburo re.

Won si gbe Kelechi lo si Amaku Teaching hospital Awka nibi ti dokita kan ti so pe o ti ku, won si gbe oku re lo si motuari fun ayewo.

Awon olopaa ni won ma to be Victor lo si ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…