Àgùnbánirọ̀ tí ń sin ilẹ̀ bàbá rẹ̀ ní Ekiti tí s’aláìsí.
Agunbaniro, Oghomwen Omoruyi Honour, ti n sin ile baba re ni Ekiti ti d’oloogbe. Iroyin ni, Honour s’alaisi ni ana June 24 leyin ti o ni ori n fo oun.
Honours setan ni eka Mass Communication lati ile iwe giga Auchi poly, won gbe lo si ile iwosan leyin ti o ni ori n fo oun, ibe lo si dake si.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…