Home iroyin Wọ́n ti pa ajínigbé, Zulu Ogwumike nígbà tí àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Rivers gba àwọn Àgùnbánirọ̀ mẹ́rin sílẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 24, 2019

Wọ́n ti pa ajínigbé, Zulu Ogwumike nígbà tí àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Rivers gba àwọn Àgùnbánirọ̀ mẹ́rin sílẹ̀.

Ni ojo Sunday, awọn ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Rivers gba awon eniyan mefa sile, awon agunbaniro merin si wa ninu won, ni agbegbe Emohua ni titi East-West.

Olopaa ago olopaa Rumuji pa ogboju ajinigbe, Zulu Ogwumike ti won mo si Black Bush nigba ti won lo sise ibi ni ibomiran.

Awon agunbaniro naa ati awon meji to n ku n rin irin ajo lati Eko lo si Port Harcourt nigba ti eon da oko won duro ti won si ni ki awon mefa naa bole, won si gbe won lo si inu igbo ni Evekwu, Emuoha Local Government Area ni ipinle Rivers. Ni ose ti o koja ni won ji won gbe ti won wa ninu ahamo fun opolopo ojo ti won to gba won sile.

PRO, Nnamdi Omoni, so ninu gbolohun pe olopaa oga olopaa Rumuji, Ademola Adebayo lo dari awon olopaa to mu awon odaran naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…