Home Entertainment Òṣìṣẹ́ LASTMA, Yesufa Olawale tí ó pàdánù ojú rè lẹ́nu iṣẹ́ ti ṣe ìgbéyàwó.

Òṣìṣẹ́ LASTMA, Yesufa Olawale tí ó pàdánù ojú rè lẹ́nu iṣẹ́ ti ṣe ìgbéyàwó.

Ni ojo Satide June 22, Yesufa Olawale, osisr Lagos State Traffic Management Authority se igbeyawo pelu ololufe re, Adenike ni Eko.

Ofisa Okawale padanu oju re lenu ise. Awon oga agba ni LASTMA ati egbe paradi ni won wa nibi ayeye naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…