Ìyàwó ti fi òògùn èkúté sí ọkọ rẹ̀ lára.
Iyawo tuntun ti fi majele ekute si oko re lara.
Masur Salihu, ni o so isele naa lori Facebook, o ni awon ore obinrin naa ni won gba a nimoran pe ki o pa oko re, ki awon le gbe fun baba olowo kan ni Abuja. O ni oko naa si n gba itoju ni ile iwosan olukoni ni Jos.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…