Ilé ẹjọ́ ti j’áwèé pé kí wọ́n lọ gbé ọ̀gá ilé isẹ́ Innoson, Innocent Chukwuma.
Ile ejo ni Ikoyi, ipinle Eko ti ja iwe pe kinwon lo gbe oga ile ise Innoson Nigeria Ltd, Innocent Chukwuma ati awon meji miiran fun esun jibiti.
Adajo Ayokunle Faji lo fi eyi lile ni ojo Mondsy June 24, ti o ni ki won gbe oga ile ise Innoson, ki won si gbe wa si ile ejo fun ejo.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…