Home iroyin Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn olè tí ń jà ní ìdí ATM ní ìpínlè Ogun.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 24, 2019

Àwọn ọlọ́pàá tí mú àwọn olè tí ń jà ní ìdí ATM ní ìpínlè Ogun.

Awon olopaa ipinle Ogun ti mu awon ole meji, Ebenezer Olubukola omo ogbon odun ati Olajide Oladejo omo odun mokandinlogbon, ti won ma n so awon ti n lo ATM ti won si ma ja won lole leyin ti won ba gba owo.

Ni ojo June 19 ni won mu won ni Sango nigba ti won n gbiyanju ati ja enikan lole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…