Home iroyin Àwọn ológun tí w’ọ̀lú Taraba, tí wọ́n ń pa àwọn èèyàn, wọ́n sì ń jó ilé.

Àwọn ológun tí w’ọ̀lú Taraba, tí wọ́n ń pa àwọn èèyàn, wọ́n sì ń jó ilé.

Awon ti n gbe ni Sondi town ni Wakari, ni ipinle Taraba,ti sa kuro ni ilu leyin ti awon ologun wo ilu won, ti won n pa awon eeyan.

Gege bi iroyin se so, awon ologun yii gbe ipinle Benue wo ilu naa ni ale. Ogun naa si wa titi di Satide, ti o si mu awon obinrin ati omode mole sinu ilu, Daily Trust reports.

Awon soja lati Takum ni won pese ana ni ojo Satide fun awon ti ogun mu mole, won si ti wa ni Wukari headquarters ti local government. Okan lara awon ti ogun o gbe lo, Jibrin Yahaya, ni ogun naa ba ni lokan je pupo nitori won ti pa opolopo eeyan, won si ti jo to “aadota ile”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…