Home iroyin Àwọn ìròyìn òmíràn nípa ajínigbé lórí afẹ́fẹ́ kìí ṣe òótọ́ – Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo.

Àwọn ìròyìn òmíràn nípa ajínigbé lórí afẹ́fẹ́ kìí ṣe òótọ́ – Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo.

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo ti so fun awon omo Naijiria ti won wa ni oko okun pe ki won ye gba gbogbo iroyin nipa aabo orile-ede gbo, nitori kii se gbogbo re lo je ooto, ati pe won do iroyin miiran nítorí oro oselu.

Igbakeji aare so eyi ninu ipade ti o se pelubawon omo Naijiria ni Townhall ni ojo Sunday June 23. Nigba ti won bere pe kini ijoba n se si oro ajinigbe ti n fo kiri lori afefe. Osinbajo ni

“ Pelu ibowo si gbogbo isele ajinigbe ti n lo ni orile ede, kii se yuntun. Koda, imii ninu awon iroyin ti a n gbo tabi ka kii se ooto, won ko so won nitori oro oselu ni. Isele nigba ajinigba wa, ko si iro nibe, amo imii ninu won kii se ooto. Gbogbo isele nipa ajinigbe ni a ma n se iwadii le lori ti o si je wipe ni ipari, itan kasan ni.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…