Home orisiirisii Arákùnrin ń béèrè fún ìdájọ́ fún àbúrò rẹ̀ obìnrin ọmọ ọdún mẹ́wàá tí wọn fi ipá bá lòpọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - June 24, 2019

Arákùnrin ń béèrè fún ìdájọ́ fún àbúrò rẹ̀ obìnrin ọmọ ọdún mẹ́wàá tí wọn fi ipá bá lòpọ̀.

Arakinrin kan, Johnprince Osita, ti leri pe oun o wa idajo fun aburo re obirin omo odun mewaa, Chisom, ti ara ile won fi ipa ba lopo opolopo igba ni ile ni won Aba, ipinle Abia.

Ninu gbolohun to do lori instagram @osyfabrics, o ni oun ma san iyekiye fun loya lati ri pe okunrin naa lo si ewon.

Osita so fun LIB ni aaro yii pe,

“ o ni isele naa ti ma n seke tipe, ti okunrin naa ma so fun oburo oun pe ti o ba so fun enikeni pe oun ma na an, o ni aburo oun ni ti oun ba ti de lati ile iwe, okunrin ma wa si inu ile awon, a si ba oun lasepo, o si ma ni ki oun ma so fun enikeni. O ni ale ana ni ago mewaa, aburo oun sojun ti o si parieo. Nigba naa ni o sese salaye oro fun mama awon.”

O ni won ti lo si ago olopaa ni aato yii, pe omo odun mewaa ni aburo oun.

Ajafetoo, Harrison Gwamnishu, ti o n mojuto isele naa ti ni won ma fi olopaa gbe okunrin naa ni osan oni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…