Home Entertainment Agbábọ́ọ́lù Cristiano Ronaldo fún àwọn Òṣìṣẹ́ ilé ìtura Greek ni ẹgbẹ̀rún pọ́ọ̀nù lọ́nà méjìlélógún pé wọ́n ò jẹ́ kí àwọn ayàwòrán rí àwòrán òun mọ̀lẹ́bí òun yà.

Agbábọ́ọ́lù Cristiano Ronaldo fún àwọn Òṣìṣẹ́ ilé ìtura Greek ni ẹgbẹ̀rún pọ́ọ̀nù lọ́nà méjìlélógún pé wọ́n ò jẹ́ kí àwọn ayàwòrán rí àwòrán òun mọ̀lẹ́bí òun yà.

A gbo pe Cristiano Ronaldo fun awin osise ile itura Greek ni opolopo owo nigba ti oun ati molebi re rin irin ajo lo si Greece.

Gege bi Daily Mail se so, agbaboolu naa ati orebinrin re Georgina, ati a we on kmo re merin lo si Westin Resort, Costa Navarino, fun odun keji amo aeonnosise ori afefe o ri aye lati ya aworan ati molebi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…