Home orisiirisii Wọ́n tí rí ẹni tí ó pa arákùnrin tí ó de láti Malaysia lẹ́yìn ọdún mẹ́sàn-àn.
orisiirisii - Orisirisi - June 22, 2019

Wọ́n tí rí ẹni tí ó pa arákùnrin tí ó de láti Malaysia lẹ́yìn ọdún mẹ́sàn-àn.

Won ti mu eni ti o pa Arthur Eze, aburo re, omo iya ati baba lo pa a.

Won pa arakunrin omo Naijiria ti o n gbe ni Malaysia ti o wale fun akoko leyin odun mesan-an ni ojo Wednesday. Ore ri kan ti so lari Facebook pe aburo re, ti n je Collins Don Collins lori Facebook pe oun lo paa nitori ilara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…