Home Entertainment Àwòrán Femi Kuti níbi ayẹyẹ AFCON ti ọdún 2019.

Àwòrán Femi Kuti níbi ayẹyẹ AFCON ti ọdún 2019.

Agba akorin, Femi Kuti, ni awon onworan pupo ni Caito International Stadium ti o gba ero 75,000, oun ati akorin omo Egypt Hakim ati Dobet Gnahore omo Ivory Coast, ti o je ara sisi ayeye Africa Cup of Nations (AFCON).

Ki won to se ayeye ṣíṣí AFCON 2019, Femi Kuti ti koko sere ni Soccer City Stafium ni Johannesburg fun ayeye sisi 2010 FIFA World Cup, eyi ti o je idije akoko ti won ma gba ni Africw, ni June 11, 2010.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…