Home iroyin Àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Delta, fìyà jẹ mí pẹ̀lú ìbọn wọn.

Àwọn ọlọ́pàá ìpínlè Delta, fìyà jẹ mí pẹ̀lú ìbọn wọn.

Arakunrin kan lati ipinle Delta ni awon olopaa ipinle Delta fi iya je oun, o ji won fi idi ibon gba oun ni ori ti o si pa oun lara.

Gege bi nnkan to so, o ni “ idi ti awon olopaa naa fi se bayii ni pe, won fi oko won di oju ọna, oun si ni ki won gbe oko won kuro ni oju ona ni won fi se oun bayii.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…