Home ÀRÒJINLẸ̀ Ọmọ obìnrin ọlọ́dún kẹta ní Uniben ti pa ara rẹ̀.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 21, 2019

Ọmọ obìnrin ọlọ́dún kẹta ní Uniben ti pa ara rẹ̀.

Omo olodun keta ni eka Medical Laboratory Science, Yunifasiti ti Benin, Christabel Omoremime Buoro, ti pa ara re.

Won ba oku omo odun mokanlelogun naa ni irole ojo Tuesdwy ni hostel re ni Plot 4, Yehudi Lane, ni Newton Street, Ekosodin, agbegbe to wa leyin Yunifasiti naa.

Won ni o mu nnkan lile lati gba emi ara re nitori orekunrin re ni oun fe ba ni ibasepo mo.

O mu oogun p’efon (Sniper) pelu olomi osan, o si ko iwe sile pe oun pa ara oun nitori eni oun nifee o nifee oun pada.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…