Home iroyin NAFDAC tí gbẹ́sẹ̀ lé títa oògùn p’ẹ̀fọn (Sniper) ní ọjà.

NAFDAC tí gbẹ́sẹ̀ lé títa oògùn p’ẹ̀fọn (Sniper) ní ọjà.

The National Agency for Food, Drug Administration and Control (NAFDAC) ti gbese le tita oogun p’efon (sniper) laaarin oja.

Adari NAFDAC, Veterinary Medicine and Allied Products Directorate, Dr. Bukar Usman, ti so ni ojo Wednesday pe International Institute of Tropical Agriculture (IITA), Ibadan ni ki awon ti n ta Sniper ye ma ta a ni aarin oja.

Gegebii o se so, sniper je oogun to ye ki won ma lo ninu oko kii se fun ilo ile. Usman ni kii se pe gbese le tita sniper patapata, amo kii se fun ilo ile afi ni oko.

O si ni kii awon ti n se oogun naa ye se ike kekere 100ml ti ko won on ti o si ma n ya awon eeyan lara ni rira. O si gbogbo oogun to ye fun lilo ni oko pe ki awon eeyan ye lo won ni ile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…