Home ÀRÒJINLẸ̀ Wọ́n yọ arákùnrin kúrò ní ipò rè ní ilé ìjọsìn nítorí irọ́ tó fà yọ nínú ẹ̀rí pásítọ̀.

Wọ́n yọ arákùnrin kúrò ní ipò rè ní ilé ìjọsìn nítorí irọ́ tó fà yọ nínú ẹ̀rí pásítọ̀.

Arakunrin kan ti so lori twitter pe won yo okunrin kan kuro lori ipo Aare egbe awon okunrin ni soisi nitori o fa iro yo ninu eri ti pasito so.

O ni pasito so eri pe oun wa oko oun lati Agungi lo si Lekki lai si epo ninu re, o ni nigba ti epo tan ninu oko naa, oun gbadurq si oko naa o si bere sini sise lai si epo ninu re.

O ni arakunrin naa wa salaye fun awon awon eeyan pe o ninbi ike epo oko se ma n sise, o ni bi epo ba tan ni ile epo, pe aye imii si se ti epo ma n wa pe epo binlita marundinlogun lo si ma n wa ninu aye yii pe o le gbe eeyan lati Lekki lo si Sagamu, pe ki i se ise adura.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…