Home iroyin Típà pa fotogirafa ní Edo.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 20, 2019

Típà pa fotogirafa ní Edo.

Tipa ti pa arakunrin kan ni ala oho Wednesday ni titi Benin-Abraka, Benin.

Oloogbe naa, God’spower, to je fotogirafa n wa oko re jade lati soobu re ni Nomayo, titi Sokponba, nigba ti o pade iju aitojo ni ago mejo koja iseju ogbon ale.

Awako tipper naa sa lo leyin ti isele naa sele, awon odo ilu si fi ibinu dana sun tipper naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…