Home ÀRÒJINLẸ̀ Òṣìṣẹ́ ilé isẹ́ rédíò ní Port Harcourt ń bẹ̀rẹ̀ fún ìdájọ́ fún ikú àbúrò rẹ̀.

Òṣìṣẹ́ ilé isẹ́ rédíò ní Port Harcourt ń bẹ̀rẹ̀ fún ìdájọ́ fún ikú àbúrò rẹ̀.

Osise ile ise redio ni Port Harcourt n bere idajo fun iku aburo re akunrin, George ti awon ole pa ni ipinle Bayelsa nigba ti n se agunbaniro.

George ati eni ti won jo n gbe ni awon oke naa ja ni ole ti won si pa won ni March odun yii.

Egbon re @honestAkpos ti n sise ni ile ise redio ni o kepe awon olopaa pe won ti dake loriniwadii oro naa. O ni oloselu kan ni o n sise labele lati je ki won gbagbe oro naa. O ke si NYSC naa pe won o da si isinku aburo oun lati igba ti isele naa ti se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…