Home iroyin Àwọn ọmọ ilé-ìwé sẹ́kọ́ndírí mẹ́ta tí kú sínú omi ní bíìṣì Akwa Ibom.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 20, 2019

Àwọn ọmọ ilé-ìwé sẹ́kọ́ndírí mẹ́ta tí kú sínú omi ní bíìṣì Akwa Ibom.

Awon ile iwe sekondiri meta, okunrin meji ati obinrin kan ti ku sinu omi ni Ibeno biisi ni Mkpanak community, ni agbegbe Ibeno local government ni Akwa ibom lojo Satide.

Awon omo ile iwe naa wa lati Upenekang community ni Ibeni local government area, won je omo ile iwe Ibena Grammar School.

Eni ti isele naa soju re, Ogbeni Asuquo Isangdighe, fotogirafa, o ni awon akekoo naa rin die, nigba ti won pada ni won be sinu omi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…