Home iroyin Ọwọ́ vigilante ti tẹ àwọn olè tí ń da àwùjọ láàmú ní ìpínlè Imo.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 19, 2019

Ọwọ́ vigilante ti tẹ àwọn olè tí ń da àwùjọ láàmú ní ìpínlè Imo.

Owo awon vigilante ti te awon ole ti n da awujo laamu ni Ochiasiato community ni Orlu, ipinle Imo.

Ni ojo Monday ni owo te won, leyin ti awon ole naa ati awon vigilante ti fi ibon taka.

Oruko inagije awon ole meji naa ni, Igbo ati AK, won wa lati Ogberuru ni Orlu LGA.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…