Home Entertainment Àwòrán Igbákejì komisona ọlọ́pàá ìpínlè Èkó tí ń fa Ẹjọ́ lórí afẹ́fẹ́.

Àwòrán Igbákejì komisona ọlọ́pàá ìpínlè Èkó tí ń fa Ẹjọ́ lórí afẹ́fẹ́.

Igbakeji komisona olopaa ipinle eko. DCP Ali Mohammed ti fi gbajumo lori afefe nitori aso re.

Ninu ipade laaarin Gomina Sanwo-Olu ati awon oloye oludaabo, DCP Ali wo aso ti zipu re o da, botinu kan naa si ti yo ni ara ewu re bi o seduro si egbe gomina.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…