Ààrẹ Buhari ti yin àwọn ọmọ Nàìjíríà tí ń gbé pẹ̀lú àlàáfíà ní òkè-òkun.
Aare Buhari ti yin awon omo Naijiria ti n gbe pelu alafafis ni oke okun, lonii ni Abuja.
Aare Progressive Ambassador of Nigeria(PAN), Jasper Emenike lo ki aare ni ile ipinle, aare si ni ki awon omo Naijiria ti n gbe ni oke okun maa foju sile ni agbrgbe won, ki won ma a ni ibasepo to peye.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…