Home iroyin Ọmọ ọdún mẹ́tàlá ṣubú lulẹ̀ lẹ́yìn tí olùkó rẹ fi ẹgba nàá ní ìgbà mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ní ọwọ́ ní Anambra.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 18, 2019

Ọmọ ọdún mẹ́tàlá ṣubú lulẹ̀ lẹ́yìn tí olùkó rẹ fi ẹgba nàá ní ìgbà mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ní ọwọ́ ní Anambra.

Omo odun metala Olive Nmmesoma Anigbogu ti daku leyin ti oluko re naa ni igba merindinlogbon ni owo ni ojo Thursday June 6, ni ile iwe Saint De Apostle High School Onitsha, Anambra.

Gege bi iya re Theodora Anigbogu se so, o ni ojo ti isele naa sele, oluko kilaasi omo oun Chidinma Uzoigwe wo kilaasi, o si ni ki awon akekoo mu ise asitilewa to fun won jade, Olive ko wa si ile iwe ni ojo to koja salaye fun oluko re pe oun o ni ise asetilewa nitori oun o wa ile iwe ni ana.

Oluko naa si na Olive ni igba merindinlogbon l’owo, bi Olive sa daku ti won si gbe lo si ile iwosan niyen.

Won pe mama re, o si sare lo si ile iwosan lati lo wo omo re.

O n gbogbo igba ni oun n gbe Olive lo si ile iwosan, pe won ti ni ki awon lo se ayewo opolo fun nitori lati igba ti isele naa ti sele ni isesi re ti yato. O si ni lati igba ti oro naa sele, oun nikan l’oun san gbogbo owo ti awon n na.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…