Home ÀRÒJINLẸ̀ Ọlọ́pàá ti gbé àwọn ọmọ Nàìjíríà ọkùnrin márùn-ún fún ẹ̀sùn pé wọ́n fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ ní ìṣojú ọkọ rẹ̀ ni orile-ede Ghana.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 18, 2019

Ọlọ́pàá ti gbé àwọn ọmọ Nàìjíríà ọkùnrin márùn-ún fún ẹ̀sùn pé wọ́n fi ipá bá obìnrin lòpọ̀ ní ìṣojú ọkọ rẹ̀ ni orile-ede Ghana.

Awon olopaa Prampram Divisional Police Command ti gbe awon okunrin Naijiria márùn-ún fún esun pe won fi ipa ba obinrin lopo nigba ti won lo jale ni Community 25 ni Tema.

Awon olopaa ti n wa awon ole naa fun igba die. Awon obinrin ti won n se ise owo(mobile money) ni adugbo ni won ma n lo ja lole, won ma gba owo ati nnkan ini won, won si ma fi ipa ba won lo.

Chief Superintendent, Cecilia Arko lo fi idi eri isele naa mule, o ni bi osu kan seyin, merin ninu awon marun naa lo si ile oko ati iyawo kan ni dede ago 3 oru lati lo j’awon l’ole.

Arko ni awon ole naa ti won n wa awon onisowo owo (mobile mobry vendor) ṣesi lo si ile oko ati iyawo naa, nigba ti won de ibe ti won ko ri owo gba, okan lara won fi ipa ba iyawo lopo ti won si yaa si ori ago won.

Ni ojo Thursday to koja, ni oko ati iyawo n rin lo ni titi, bi iyawo se ri eni ti o fi ipa ba oun lopo ni yen, oun ati oko re si pariwo, won si ri odaran naa mu.

Won fa a le olopaa lowo, o si mu won lo si ibi tibawon iyoku re wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…