Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn olè ló jí 6.8 mílíọ̀nù ní ilé ìfihàn onírúurú ẹranko ní Kano, kì í ṣe ọ̀bọ(Gorilla) – Adarí ọlọ́pàá tí Ìpínlẹ̀ Kano.

Àwọn olè ló jí 6.8 mílíọ̀nù ní ilé ìfihàn onírúurú ẹranko ní Kano, kì í ṣe ọ̀bọ(Gorilla) – Adarí ọlọ́pàá tí Ìpínlẹ̀ Kano.

Adari ile ifihan oniruuru eranko ti Kano, Umar Yusuf Umat, ti ni kii se obo lo gbe 6.8milionu min.

Umar ni awon ole ni ji owo naa, pe ko si obo (gorilla) ninu ile ifihan ẹranko naa. O ni:
“olori olodaabo wo lo pe mi ni oru ojo Sunday Zjune 9, pe awon ole ti wo ofisi wa, pelu ofisi ti owo ma n wa. Ni nnkan bi ago mefa aaro, mo lo si ibise mo si ba ofisi mi ati awon to ku ni sisi. Esekese ni mo pe DPO, sharada police station ti mo si fi ejo sun. Emi mo pe ole lo ji owo gbe kii se obo.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…