Home iroyin Olè gbé òrùka ìgbéyàwó arábìnrin mìn.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 17, 2019

Olè gbé òrùka ìgbéyàwó arábìnrin mìn.

Àwọn RRS ti ipinle eko,ni Oshodi ati lara CMS ti mu ole inu tirafiki ti o gbe oruka arabinrin kan min, leyin ti o ni oun ma paa, pelu awon meta kan.

Eni ti o gbe oruka min, Taofeek Adebayo, 19, pelu ikeji re, Toheeb Tijanu, 20, ni won mu ni Oshodi-Oke leyin ti won gba yeri eti goolu ati oruka igbeyawo lowo awon obinrin meji ninu oko sienna.

Won mu awon meji to ku, Samson Olywa,20 ati Micheal Amodu Adamu, 22, ni ale nigba ti won n se ise ibi lowo ni CMS.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…