Home Entertainment Mercy Aigbe ń kí ara rẹ̀ fún ayẹyẹ ọjọ́ bàbá.

Mercy Aigbe ń kí ara rẹ̀ fún ayẹyẹ ọjọ́ bàbá.

Mercy Aigbe n ki ara re lori instagram fun ayeye ojo babs. O ni “ mo ki ara mi ku ayeye ojo baba, si gbogbo baba dada ati awon iya ti n da omo to ti won n se aye baba ati iya…. Okunrin yoo ma a fun wa ni agbara, aagun wa lori awon omo wa o ni ja si asan.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…