Home ÀRÒJINLẸ̀ Ọlọ́pàá ti gbé àwọn obìnrin mẹ́fà tí wọ́n má ń jí ọmọ gbé ní ìpínlè Imo.
ÀRÒJINLẸ̀ - orisiirisii - Orisirisi - June 14, 2019

Ọlọ́pàá ti gbé àwọn obìnrin mẹ́fà tí wọ́n má ń jí ọmọ gbé ní ìpínlè Imo.

Awon oloopaa ipinle Imo ti gbe awon obinrin mefa ti won ma n ji omo gbe ti won si ma n ta won. Awon obinrin naa ni Perpetual Iwuji omo odun merindinlaadota, Isong Ifara omo odun merindinlaadota, Immaculate Edward omo odun mokanlelogbon, Grace Nwachukwu omo odun mejidinlogota, Ifeoma Ndubuisi omo odun metadinlogbon ati Stephen Ezenwa omo odun. mokanlelogbon.

Olopaa ti ipinle naa ti ma n ba awujo soro, o je Alabojuto olopaa, Orlando Ikeokwu, ni awon odaran naa,ma n ji awon omode gbe ni ile iwe, ile ajosin ati awon ibi to je gbangba miiran, pe won mu won nigba ti okan lara won Immaculate Edward, omo Okonde ni ipinle Cross River lo ki orekunrin re, Ifara Isong ni Eziama Logara ni Ngor Okpala Council, ti o si ji omo márùn-ún ti won fi so lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…