Arábìnrin s’aláìsí lẹ́yìn tó bí ìbẹta ní èkejì.
Arabinrin kan ti salaisi leyin to bi ibeta ni ekeji.
Arabinrin Chinyere Amadu ati Ogbeni Emmanuel Amadi bi awon ibeji ni ojo Democracy, June 12. Eyi ni igba keji tinwon ma bi ibeji. Won bi akoko ni odun mefa seyin.
O se ni laaanu pe leyin ti Arabinrin Chinyere bi awon ibeta yii ni Elele Alimini, Emolga ni ipinle Rivers, o salaisi.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…