ìdíje FIFA Women World Cup: Naijiria na Korea 2 – 0.
Awon agbaboolu obinrin ti orile-ede Naijiria ti ni anfaani lati koja si ipele to n bo ninu FIFA Women World Cup ti n lo lowo leyin ti won na South Korea ni 2 – 0,
Agbaboolu ipinle South Korea, Kim Doyeon lo fun wa ni goolu kan, ti Asisat Oshoala si mu goolu keji.
Leyin ti Norway ti na Naijiria pelu 3 – 0 ni ipele akoko.
Naijiria maa dojuko France ni ipele to keyin ki o to dori ipele to gaju.
Won ma gba gaamu na ni june 17 ni Roazhon Park ni Rennes.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…