Home iroyin Èèyàn márùn-ún ti farapa lẹ́yìn tí mọ́ọ̀lù ní Port Harcourt gbiná.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 13, 2019

Èèyàn márùn-ún ti farapa lẹ́yìn tí mọ́ọ̀lù ní Port Harcourt gbiná.

Eeyan márùn-ún ti farapa leyin ti moolu Port Harcourt ni ipinle Rivers gbina lojo Wednesday June 12.

Agbenuso awon olopaa ipinle Rivers, Nnamdi Omoni ni o fi idi eri isele naa mule pe bakiri ni ina naa ti bere ki o to mu gbogbo moolu, amo won o ti mo nnkan to fa ina.

Won ni ko pe si igba ti awon to n sise nibe pa ina naa ki awon pananpan to de ibe. Moolu naa wa ni agbegbe Old GRA ni Port Harcourt, ko si jina si gaati ile ijoba.

Omoni ni awon to farapa n gba itoju lowo ni Rivers State University Teaching Hospital (RSUTH), awon olopaa si ti bere iwadii lori isele naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…