Home ÀRÒJINLẸ̀ Àwọn olè pa arábìnrin, wọ́n jà á ní olè, wọ́n sì tì í jáde nínú ọkọ̀ ní ìhòòhò.
ÀRÒJINLẸ̀ - iroyin - orisiirisii - Orisirisi - June 13, 2019

Àwọn olè pa arábìnrin, wọ́n jà á ní olè, wọ́n sì tì í jáde nínú ọkọ̀ ní ìhòòhò.

Arabinrin kan ti won n pe ni, Abimbola Ayanwale Modinat, ti salaisi leyin ti awon ole jaa lole, ti won si tii jade ninu oko ti n rin ni idi-iroko, ni agbegbe Anthony Village ni ipinle Eko ni ojo Tuesday, June 11.

Iroyin ni, ibi ise ni Abimbola ti n bo, ki o to si oko awon odaran wo. Ninu iran ajo naa ni won ti jaa lole, won paa, won si tii jade ni ihoho omoluabi ni iwaju Domino’s Pizza ni ago mokanla ale ni ojo Tuesday, June 11.

Won gbe isele naa lo si Anthony Village Police Station lesekese, won si gbe oku re lo si mosuari Lagos State University Teaching Hospital (LASUTH).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…